Tope Alabi – Oluwa O Tobi [Audio+Video+Lyrics]

Tope Alabi – Oluwa O Tobi [Audio+Video+Lyrics]

November 18, 2018 0 By Cypher9ja

Described as the most popular indigenously composed Yoruba worship song in Nigeria, Oluwa O Tobi is a hit track from the famous gospel yoruba songstress Tope Alabi from her Album Alagbara which was released in 2012.

Well laced with essentially deep lyrics and graced with condensed metaphors, worshipers across Africa agree that this tune is surely one to reckon with.

Listen, download and enjoy!

FREE MP3 DOWNLOAD

Tope Alabi – Oluwa O Tobi Lyrics

Oluwa o tobi
o tobi o, o tobi ×2
kos’eni tale fi s’afiwe re o
o tobi o, ko s’eda tale fi s’akawe re o
o tobi o oluwa ×2

O tobi o, oluwa giga
lorile ede gbogbo
gbigbega ni o
pupopupo ni o
o koja omi okun
at’osa o ga po
ajulo ose julo

Oba Lori aye o tobi o eh
agbani loko eru
olominira ton deni lorun
ofi titobi gba mi
lowo ogun t’apa obi mi oka
olugbeja mi to ba r’ogun
lalai mu mi lo to segun
Akoni ni o
Boti tobi to oo
lanu re tobi
boti tobi se o
lododo re tobi o
o tobi tife tife
oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije minu
aye gbogbo alai le tan
ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
akoko otobi, o tobi o